Published online by Cambridge University Press: 11 August 2017
Ìlú Ẹdẹ Màpó Àrógun
Ìlú Ọba Tìmì Àrólé
Ìlú àwon aj’ó lógun
Ati ṣetán lati gbée ga,
Ọmọ Ẹdẹ Màpó Àrógun
Ọmọ ají làlà ọ́ṣọ ni
Fọjọ́ gbogbo dára bí egbin
K’á so'wọ́pọ̀ ká gbélu waga,
Ìsọ̀kan ṣà l'agbára wa,
Gbogbo ohun tó bá ti dára,
Ṣe-bí Ẹdẹ ni wọ́n fi n wé,
Fàlà sọ̀dọ̀ béléwú báwo,
Wọn á bi'ra wọn ṣ’o dára bí t’Ẹ́dẹ,
Wọn sì dá’hùn pé ó dára bí t’Ẹ́dẹ,
Bó ṣe gúsù,
Bó ṣ àríwá,
Ìlà oòrùn tàbí 'wo oòrùn,
Kò sí-bì kan tó d à-bí ilé,
Torí ilé làbọ̀ sinmi oko,
À’ m bẹ̀ Ọ, Ọba Olúwa,
Gbàdúrà wa lórí ìlú wa,
Kí ìlú Ẹdẹ kí ó ta wọ́n yọ,
Kí Ọlọ́run o ràn wá lọ́wọ́
Àmín
Ede, the town of Màpó Àrógun
The town of (Ọba) Tìmì
The town of great warriors
We are ready to lift it to greatness
Descendants of Ede Màpó Àrógun
Descendants of those who cherish beauty
Beautiful everyday like a zebra
Let us join hands to lift our town to greatness
In unity lies our strength
Everything that is good
Is usually compared to Ede
In dispute about the standard of things,
People often ask if it is as good as Ede
Their reaction is that it is as good as Ede
In the South
In the North
In the East or West
There is no place like home
Because home is the place of rest after work
We are praying to You, God
Accept our prayers over our town
For Ede to triumph over others
May God help us
Amen
To save this book to your Kindle, first ensure [email protected] is added to your Approved Personal Document E-mail List under your Personal Document Settings on the Manage Your Content and Devices page of your Amazon account. Then enter the ‘name’ part of your Kindle email address below. Find out more about saving to your Kindle.
Note you can select to save to either the @free.kindle.com or @kindle.com variations. ‘@free.kindle.com’ emails are free but can only be saved to your device when it is connected to wi-fi. ‘@kindle.com’ emails can be delivered even when you are not connected to wi-fi, but note that service fees apply.
Find out more about the Kindle Personal Document Service.
To save content items to your account, please confirm that you agree to abide by our usage policies. If this is the first time you use this feature, you will be asked to authorise Cambridge Core to connect with your account. Find out more about saving content to Dropbox.
To save content items to your account, please confirm that you agree to abide by our usage policies. If this is the first time you use this feature, you will be asked to authorise Cambridge Core to connect with your account. Find out more about saving content to Google Drive.